Skip to content

Yorùbá

Ni 3rd May 2012, awon eniyan ni gbogbo Londonu ni a o fun ni anfanni lati dibo fun Onidajo ilu ti Londonu ati ile igbimo asofin Londonu.

Ibo yi da lori yiyan eniti yoo sasoju re ati ti yoo se ipinnu fun opolopo eka igbe aye ojojumo re- lati abenu, ise oko agbegbe, awon Olopa, si ayika alawo ewe, ojulowo afefe ati igun merin Trafalgar.

Fun o lati le dibo o gbodo:

  • 18 tabi jube ni 3rd may 2012
  • je Biritisi,  ijoloro isokan tabi omo ilu isokan Yuropu
  • maa gbe ni Londonu
  • Foruko sile fun idibo

Ni yiyan yii, wa ni idibo meta:

  • idibo kan fun Onidajo ilu ti londonu
  • okan fun eniti yoo sasoju agbegbe re
  • Okan fun awon eniyan ti yoo sasoju gbogbo Londonu

Nigba ti o ba lo dibo, a o fun o ni awon iwe idibo meta

Lati mo si nipa idibo yii, ibi idibo, igba idibo ati bi a o se itewobo awon iwe idibo re meteta jowo gba awon ewe kekeke wa ni ede Yoruba nisale. Awon iwe isafihan wa ni Yoruba bi o ba fe lati so. Fun awon elomiran nipa nini ohun ninu idibo yii.

Jowo mo wipe gbogbo iwe idibo ni o wa ni Geesi ti ko si si awon ohun itumo ni idi idibo. Bi o ba fe, o le mu enikan pelu re lo si ibi idibo lati ran o lowo bi o tile je pe o gbodo towobo iwe idibo fun ara re pelu ohun ti o yan.

Bi o ba nilo itoni nipa bi wa se foruko sile fun idibo, jowo losi www.aboutmyvote.co.uk

Ni ohun tire. Dibo ni 3rd May.

Useful downloads

Language

All languages